View Full Version : Yoruba nìkan
- Ikanni ero ayelujara Nigeria www.nigeria.gov.ng , n se aare.
- Ijakule ti egbe oselu PDP ti fun awon omo ile Nigeria ni o mu ki won ni igbagbo ninu egbe APC ti won sese da sile- Ibrahim Shekarau
- Oseese ki Victor Moses kopa ninu asekagba ibije AFCON
- igbakeji alaga egbe oselu APGA, oloye Uche Ejike ti ni egbe oselu All Progressive Congress yi o sese di didasile yio tuka laarin osu mefa.
- Joseph Yobo tii se Balogun Super Eagle ti ni o n gba lero lati lo f’eyin ti leyin idije AFCON ti o n lo lowo.
- Sule Lamido ti se gomina ipinle Jigawa ti so wipe idarapo awon egbe oselu alatako ko lee so eso rere
- Awon Super Eagle ni won yio maa gba egberun l’ona Ogbon owo Dollar ($30,000) latari bi won se kogoja si ipele ti o kan ninu idije AFCON ti o n lo lowo.
- Awon Super Eagle ni won yio maa gba egberun l’ona Ogbon owo Dollar ($30,000) latari bi won se kogoja si ipele ti o kan ninu idije AFCON ti o n lo lowo.
- Ọ̀wọ́nrín Ṣ'ogbè
- S/N LGA ACN LABOUR PDP 1. Akure North 5,671 10,857 4,916 2. Akoko North East 8,693 12,153 6,847 3. Akoko North West 9,138 11,675 7,847 4 Ifedore 5,522 11,062 3,978 5. Ile Oluji/Oke Igbo 9,061 11,945 6,521 6. Irele 5,066 9, 435 9,341 7
- Eyi ni esi idibo Gomina ipinle Ondo bi o se n wole
- Awon obinrin metalelogbon (33) je Olorun nipe nigbati oko won bo sinu odo.
- Awon arinriajo lo si ile mimo mecca lati Nigeria meedogun ni won ti ku si orileede Saudi Arabia
- Awako oko ero kan ku s’inu salanga ni ilu Eko
- Oga agba awon Olopa ti ko awon olopa kuro leyin awon ti won di ipo owelu mu
- Kede ijoba pajawi lori eto Ilera -David Mark
- E topipipin oro awon NULGE pe Kayode Fayemi n yo owo awon ijoba ibile ti ipinle Ekiti.
- Kwesi Appiah tii se oluko egbe agbaboolu orileede Ghana ti ro awon agbaboolu ile naa lati lakaka gba ife eye ti AFCON 2013 Fun aare John Atta ti oku
- El-Rufai ti ro aare Jonathan lati fi ipo re sile.
- Laipe ni a o pari papako ofurufu ti ilu Ido Osun. Gomina Aregbesola
- Awon agbebon kolu ile ijosin Deeper life
- Eniyan meji ti jona ninu ijamba oko
- Igbo ni ipo aare Nigeria to si leyin Jonathan: Igbozuruwe
- Blessing Okagbare ni o ru ipo ninu idije 100m Olympics
- FÍFI OJÚ ÌMỌ̀ ÌṢỌWỌ́-LO-ÈDÈ WO EWÌ ÌGBÀ LONÍGBÀÁKÀ TÍ OLÚYẸMISÍ ADÉBỌ̀WÁLÉ KỌ
- ÌFOJÚ TÍỌ́RÌ ÀŚÀ ÌBÍLẸ̀ WO ÌWÉ ERÉ-ONÍTÀN ÀGBÀ TÍ Ń YỌ́’LẸ̀ DÀ TÍ OLÚ OWÓLABÍ KỌ
- Ewì: Àkókò ń lọ
- Yorùbá nìkan l'a máa sọ níbí.
Powered by vBulletin® Version 4.1.11 Copyright © 2013 vBulletin Solutions, Inc. All rights reserved.
Search Engine Friendly URLs by vBSEO 3.6.0 ©2011, Crawlability, Inc.