
07-30-2008, 07:48 PM
|
 |
Olùkọ́ Ọbádélé
is looking for moderators AND educators
Abibikasa Wura
|
|
Join Date: Aug 2006
Age: 29
Posts: 2,893
Thanks: 9
Thanked 59 Times in 50 Posts
Rep Power: 9
|
|
Dr. John Henrik Clarke Oriki - O. Kambon & Ajisafe Adetutu

Oríkì Baba Kíláàkì
¿nikêni tí kò bá mötàn tán l÷lêtàn á máa tàn j÷ Tá ni kò möbátan Baba Ìtàn; Òpìtàn t’ó mötàn tán? Afôjú t’ó lajú t’ó sì «áájú àwæn olójú Bêë sì ni ó ran àwæn ìrandíran mìíràn lôwô láti ríran Ìbátan Baba Ìtàn; Òpìtàn t’ó mötàn tán Ælálá ñlá t’ó mönà àtìgbanilà Atônà t’ó lànà fún wa látàná T’ó tanná bíi ìtàn«an onítànmôlë kítàn náà lè máa tàn kálë Òõköwé t’ó mú kí ilé ìkàwé kún fún ìwé Ìbátan Baba Ìtàn; Òpìtàn t’ó mötàn tán Baba o mæ àná kí àwa náà lè mæ öla À«é, “òwúrö ni yóò fi hàn bí alê yóò ti rí” Orísun Ì«ökan l’à bí i sí Òkun Ìgbêkëlé-tara-÷ni ni wôn jáláìsí sí Àmô, a ñ kì í, a ñ sà á o «áà ní o ò m÷ni t’á ñ sörö yìí Háà! Baba Kíláàkì, ìwæ l’à á ñ ké sí Ìbátan Baba Ìtàn; Òpìtàn t’ó mötàn tán Æmæ tuntun t’ó bôdúndé tìdùnnú tìdùnnú Tí ó kun àgbélébùú ní dúdú Ælôpælæ t’ó lôpælæ lôpölæpö T’ó fimú fínlë fún ìmö ìjìnlë láti ìbërë ìpilë láti ìpínlë dé ìpínlë Alákæsílë o, alát÷nudênu o, kò sóhun tí ò kô Àyàfi èyí tí kò ì tíì rí, tí kò ì tíì gbô Balógun àwæn jagunjagun ayé-dúdú T’ó gbé pósí wá fún ÷nikêni t’ó bá fê bá a «e aríyànjíyàn T’ó gbé ÷nikêni t’ó bá fê bá a jà dé sàárè ¿yin kìí bá òkúta jà
Èso kìí sì bá öb÷ jà
Bêë sì ni dígí kò gbædö pe òkò níjà òyìnbókóyìnbó t’ó bá fê bá Baba Kíláàkì jà gbædö gbaradì gbígbé ibojìììììììì! Ìbátan Baba Ìtàn; Òpìtàn t’ó mötàn tán T’ó ñ f÷së rin ìrìn-alágbára ñlá
T’ó ní, nõkankíõkan tí ò bá j÷mô òmìnira ni k’á gbé e dànù
Ìbátan Baba Ìtàn; Òpìtàn t’ó mötàn tán Ælôkö-Ilé, jöwô gbé wa délé, jöwô gbé wa délé Gbé wa délë Adúláwö Iná kú, ó feérú bojú Iná kú, ó feérú bojú
Ögëdë kú, ó fæmæ rôpò Tá ni yóò jogún Balógun Àwa náà l’a máa jogún Balógun Tá ni yóò jogún Balógun Àwa náà l’a máa jogún Balógun Tá ni yóò jogún Balógun Àwa náà l’a máa jogún Balógun un un un ùn ùn ùn!!!My feet have felt the sands
Of many nations,
I have drunk the water
Of many springs.
I am old.
Older than the pyramids,
I am older than the race
That oppresses me,
I will live on...
I will out-live oppression.
I will out-live oppressors."DETERMINATION"
July 16, 1998
|