Communiversity

Afrikan Language Institute => Yoruba Language Resources => Topic started by: Samuel Ata Kwabena Ma'at on Mar 13, 2016, 11:21 AM

Title: Mo ní ibèèrè-gctid178266
Post by: Samuel Ata Kwabena Ma'at on Mar 13, 2016, 11:21 AM
Ẹ kú ọjọ́ mẹ́ta, olùkọ́. Mo ní àwọn ìbèèrè mejí.

Báwo ni a ṣẹ ń sọ  "Cheetah"?

Àti

Kí ìyàtọ̀ larin "wí" ati "sọ"?
Title: Mo ní ibèèrè-gctid178303
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Mar 13, 2016, 05:33 PM
Orúkọ rẹ̀ ni "Ọ̀wàwà" http://www.theyorubablog.com/cheetah-owawa/ (http://www.theyorubablog.com/cheetah-owawa/)
Ìgbà tí a máa ń sọ àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyẹn l'ó mú kí wọ́n yàtọ̀ sí ara wọn.

Àpẹẹrẹ kan ni pé: a lè sọ pé "Mo sọ wí pé..." ṣùgbọ́n a kò lè sọ pé *"Mo wí sọ pé..."