Mo kí yín.
Kí ni ìtúmọ̀ "tótó o..." ni èdè òyìnbó? I know it is a way to show respect to elders, but how does it translate, for example the context:
"Tótó o, àgbà, ó ṣe bíi òwe".
Ẹ ṣeun síwájú.
QuoteHi Free-quency;253794 wrote: Mo kí yín.
Kí ni ìtúmọ̀ "tótó o..." ni èdè òyìnbó? I know it is a way to show respect to elders, but how does it translate, for example the context:
"Tótó o, àgbà, ó ṣe bíi òwe".
Ẹ ṣeun síwájú.
Òo,
Kò sí irú ọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀yẹn ní èdè/àṣà òyìnbó tí a ní láti sọ nígbà tí a pa òwe níwájú àgbà. Àmọ́, nínú irú gbólóhùn báyìí, a lè sọ pé ìtúmọ̀ rẹ̀ ni "please excuse me/excuse my language."
Kò tọ́pẹ́ o.
QuoteObadele Kambon;254158 wrote: Òo,
Kò sí irú ọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀yẹn ní èdè/àṣà òyìnbó tí a ní láti sọ nígbà tí a pa òwe níwájú àgbà. Àmọ́, nínú irú gbólóhùn báyìí, a lè sọ pé ìtúmọ̀ rẹ̀ ni "please excuse me/excuse my language."
Kò tọ́pẹ́ o.
Ó dáa. Ò yé mi nísisíyì.
Sent from my iPhone using Abibitumi Kasa mobile app (http://r.tapatalk.com/byo?rid=88213)