Communiversity

Afrikan Language Institute => Afrikan Language Resources => Topic started by: Ɔbenfo Ọbádélé on Oct 22, 2006, 04:28 AM

Title: Akan and Yoruba: Mmɛbusɛm/Òwe-gctid24698
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Oct 22, 2006, 04:28 AM
Yorùbá
 
Bí irọ́ bá sáré fún ogún ọdún, ọjọ́ kan ni òótọ́ máa bá a.

 
If lies run for twenty years, in one day, truth will catch it.
 
 Akan
 
Ɔtorofo de mfe apem tu kwan a, ɔnokwafo de da koro tiw no to no.

 
Whereas the liar takes one thounited snakesnd years to go on a journey, the one  who speaks the truth follows and overtakes the liar in a day.
Title: Akan and Yoruba: Mmɛbusɛm/Òwe-gctid24700
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Oct 22, 2006, 04:42 AM
Yoruba
 
Gbogbo àwọn tí Ọlọ́run bá so pọ̀, kí ẹnikẹ́ni má ṣe ya wọ́n.
 

All those who Olorun joins together, may noone tear them apart
 
 Akan
 
Nkoma a Onyame de atoa mu no, nnipa ntumi nte mu.

 
Hearts that Onyame has joined together, human beings cannot tear apart.
Title: Akan and Yoruba: Mmɛbusɛm/Òwe-gctid24702
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Oct 22, 2006, 04:44 AM
Yoruba
 
Lásán àjèjì lójú, kò fi ríran tó ọmọ onílẹ̀

 
For no reason the stranger/visitor has eyes, he or she doesn't use them to see up to the standard of the citizen of the country.
 
 Akan
 
Ɔhɔhoɔ ani akɛseakɛseɛ, nanso ɔmfa nhu hwee
.
 
Though the strangers eyes may be big, he/she doesn't use them to see anything.
Title: Akan and Yoruba: Mmɛbusɛm/Òwe-gctid24704
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Oct 22, 2006, 04:45 AM
Yorùbá
 
Ọmọ tí ó mọ ọwọ́ wẹ̀ l’ó bá àgbà jẹun.

 
A child who knows how to wash his or her hands joins the elders in eating.
 
 Akan
 
Akwadaa hu ne nsa horɔ a, ɔne mpaninfoɔ didi.

 
A child who sees his hands and washes them, he/she and elders eat.
Title: Akan and Yoruba: Mmɛbusɛm/Òwe-gctid24706
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Oct 22, 2006, 04:45 AM
Yorùbá
 
Ahọ́n àti eyín máa ń jà lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan

 
The tongue and the teeth be fightin' every so often.
 
 Akan
 
Ɛse ka tɛkrɛma, nanso wɔte bom.

 
The teeth bite the tongue, but they live together.
Title: Akan and Yoruba: Mmɛbusɛm/Òwe-gctid24707
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Oct 22, 2006, 04:46 AM
Yoruba
 
Bí ọ̀rọ̀ bá pẹ́ nílẹ̀, gbígbọ́n ní í gbọ́n.
 

If an issue lasts for a long time in the land, wisdom will become wise.
 
Akan
 
Asɛm kyɛ a, nyansa ba ho.

 
If an issue lasts for a long time, wisdom comes to it.
Title: Akan and Yoruba: Mmɛbusɛm/Òwe-gctid24708
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Aug 10, 2007, 04:08 PM
Yorùbá

Màálù tí ò nírù, Ọlọ́run l’ó máa ń bá a lé ẹṣinṣin.

The cow that doesn’t have a tail, Olorun helps him/her chase away flies
 
Akan

 Aboa a ɔnni dua no, Onyame na ɔpra ne ho.
The animal that doesn’t have a tail, It is Onyame who sweeps his/her body
Title: Akan and Yoruba: Mmɛbusɛm/Òwe-gctid24709
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Aug 10, 2007, 04:10 PM
Yorùbá

Ẹni Ọlọ́run kò pa, ọba kan kò lè pa á
.
The person who Olorun doesn’t/didn’t kill, a ruler cannot kill
 
 Akan

Onyame ankum wo a, wonwu.

If Onyame hasn’t killed you, then you don’t die
Title: Akan and Yoruba: Mmɛbusɛm/Òwe-gctid24710
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Aug 10, 2007, 04:12 PM
Yorùbá

Kí a fi ọwọ́ wẹ ọwọ́ ni ọwọ́ fi mọ́.

Using one hand to wash the other is what makes the hand clean
 
Akan

Benkum dware nifa na nifa dware benkum
.
The left washes the right and the right washes the left
Title: Akan and Yoruba: Mmɛbusɛm/Òwe-gctid24711
Post by: Ɔbenfo Ọbádélé on Aug 10, 2007, 04:13 PM
Yorùbá

Oorun l'a fi dán ikú wò.

Sleep is what we use to test out what death is like.
 
 Akan

Wonnim owu a, hwɛ nna.

If you don't know death then look at sleep.