Sponsored Community Message Browse Free. Go deeper with Full Access. Free visitors can browse public knowledge. Full Access unlocks participation, member areas, and an ad-free experience.

Homework-2nd Lesson-gctid219529

Started by Ekundayo, Jan 31, 2017, 03:22 AM

Previous topic - Next topic
Ẹkọ́ Kejì-Ìkíni ìlera/Ìkíni láàrin ọjọ́

I. Dáhùn bí ó ṣe yẹ

1. Báwo ni? Dáadáa ni
2. Ẹ kú ọjọ́ mẹ́ta. Àtọjọ́ kan pẹ̀lú.
3. Ìpàdé wa bíi oyin. Àṣe.
4. Kì l' ó ń ṣẹlẹ̀? Kò sí nǹkankan.
5. Mo kí yín. Òo.
6. Ó dàbọ̀.

II. Ìfiwé
1. Ìyá ńkọ́. Wọ́n wà
2. Bá mi kí gbogbo ilé. Òo. Wọ́n á gbọ́!
3. Kí l'ó ń ṣelẹ̀? Kò sí nǹkankan.

III. Ìfọ̀rọ̀sípò
1. Kí l'ó ń ṣelẹ̀?
2. Bá mi kí gbogbo ilé
3. O ṣé! Ó dàbọ̀ o.
4. Àwọn ọmọ ńkọ́?
5. Òo dáadáa ni.
6. Kò sí nǹkankan.
7. Mo ti fẹ́ máa lọ
8. Wọ́n á gbọ́.

IV. Ìdáhùn
1. Ẹ káàsán. Òo. E káàsán
2. Báwo ni? Òo. Dáadáa ni.
3. Iṣẹ́ ńkọ́? O wà.
4. O ṣé! Ò dàbọ̀ o. Òo.
5. Bá mi ḱí gbogbo ìlé. Òo! Wọ́n á gbọ́!
6. Baba ńkọ́? Wọ́n wà.

V. Ìtúmọ̀
1. Wọ́n wà. They are fine.
2. Kí l'ó ń ṣẹlẹ́? What's happening?
3. Ẹ káasán. Greetings for the afternoon.
4. Ìyá ńkọ́? How is your mother?
5. Mo ti fẹ́ máa lọ. I'm ready to leave.
6. Ó dàbò. Goodbye.
7. Bá mi kí gbogbo ilé. Greet your house for me.
8. Òo. Wón á gbọ́! Ok! I'll tell them.
9. Kò tọ́pẹ́. You are welcome
10. Àwọn ọmọ ńkọ́? How are the children?

VI. Ó kàn mí
1. How about mother? Ìyá ńkọ́
2. How is it? Báwo ni.
3. They are fine. Wọ́n wà
4. You're welcome. Kò tọ́pẹ́
5. Thank you. O/Ẹ ṣé
6. It's not worthy of thanks. Kò tọ́pẹ́
7. How are the people of the household? Bá mi kí gbogbo ilé
8. It's fine.
9. Nothing's up. Kò sí nǹkankan.
10. Goodbye. Ò dàbọ̀

Kindly post this in the homework section. Ẹ ṣé.
__________

Ọbádélé Kambon, PhD
Nana Kwame Pɛbi Date I, Ban mu Kyidɔmhene, Akuapem Mampɔn
Senior Research Fellow & Research Coordinator - Language, Literature and Drama Section
Institute of Kmtyw Studies - College of Humanities
Editor-in-Chief - Ghana Journal of Linguistics
Secretary (2015-2020) - Kmtyw Studies Association of Kmt
+233249195150 / +19192836824 | me@obadelekambon.com
www.obadelekambon.com | www.abibitumi.com
Room 115 IAS Kwame Nkrumah Complex
University of Ghana - Legon
Alternate Email: obkambon@staff.ug.edu.gh



Ọbádélé Kambon App



Abibitumi.com App